Awon Orin Chief Commander Ebenezer Obey Ati Osere Re by Ojogbon Funso E Olufyitan

₦2,000
Qty:
Iwe yi dabi Akomolade. Orin kiko ni de Yoruba kun fun oye ati imo oniruru ninu ede na. Awon orin inu iwe yi nkoni ni owe, bi a se ngbadura, itan arikogbon ati bebelo. Ati odo ni mo ti nko owe Yoruba ninu orin osere apala bi ti ologbe Haruna Ishola.

Iwe yi kise Bibeli tabi Quarani, Sugbon bi ati nko adura gbigba, pelu ogbon ati oye ninu awon iwe mimo na, a le ko iru eleyi ninu Orin Obey to wa ninu iwe yi. O wa fun omode ati agba.
  • Availability: 5 In Stock

Write Review

Note: Do not use HTML in the text.