Ewa Enu Yoruba By Olu Lasekan

₦500
Qty:
Yoruba lo lede, Yoruba lo lasa. Yoruba lo ni ka pede ka fa komookun yo. E je kawo ewa ede Yoruba kan wo. Eni to ba laya ko pe awon gbolohun naa leemarun-un lera lera.
1. Ijapa n gboke gope.
2. Alira n lora rela.
3. A padaba l'aba baba; a o fun baba alaba l'adaba je.
4. Labalaba subu l'Alaba, l'Alaba ba laa labara.
  • Availability: 998 In Stock

Write Review

Note: Do not use HTML in the text.

Related products